You are implored to
join the NaijaLyrics Club as there are so many opportunities you get by joining. It will do us more good, if you also tell a friend about this site. That won't take your time, I think.
Tell a friend Now.
"Awilele" by Beautiful Nubia
Song Title: Awilele
Artiste: Beautiful Nubia
From Album: Awilele
Year : 0000
Genre :
Lyrics:
Ma a dun, ma a dun, oni'lu mi, ma a dun, ma a dun
Ma a fon, ma a fon, onifere yi o, ma a fon, ma a fon o
E ma a ko, e ma a ko, eyin elegbe mi, e ma a ko, e ma a ko
Ani ko ma a ro - Awilele!
L'eti elegan o - Awilele!
L'eti k'enimamani o - Awilele!
Awon asenibanidaro - Awilele!
Won so'le owo d'ahoro - Awilele!
Won ti so'le olora d'asale, won so'le owo d'ahoro o
Tani o r'ogun - talo fe j'agun?
Ogun oro ma lo kan yio - o de, jagun jagun de!
Ogun oro l'oma kan yio - o de, jagun jagun de!
Eni ba le ko k'o ma a ko, eni ba le so ko ma so
Eni ba le ko l'orin o - a ni e maa so 3ce
Ogun oro ma lo kan yio - o de, jagun jagun de!
Ogun oro l'o ma kan yio - o de jagun jagun de!
So daa k'omo enikan maa wo'so tuntun l'ojojumo
K'omo enikan maa w'akisa kiri
So da k'omo enikan ma re'lewe olowo nla
K'omo enikan maa re suuku abe'gi
Ani to ba da, e je a ma ba lo - e je a ma ba bo
To ba da, e je a ma ba lo- yo kangun sibi kan
A o d'eniyan l'ola o
Awa yio d'eniyan l'ola ye
A o wo'so olowo, awa yio wo bata oye
A o wo'so olola, awa yio wo bata, ye
A o d'eniyan l'ola o...
Posted by: