Browse artistes: A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9      Search :

REQUESTED LYRICS

  • Pakurumo - Wizkid
  • if you wine for me - Kas
  • beef - MI
  • Everything - 9ice ft tiwasavage
  • Hustle - MI

You are implored to join the NaijaLyrics Club as there are so many opportunities you get by joining. It will do us more good, if you also tell a friend about this site. That won't take your time, I think. Tell a friend Now.

"Ijoba Orun" by Lara George

View Video
Report Error
Song Title: Ijoba Orun
Artiste: Lara George
From Album: Single
Year : 2008
Genre :
Lyrics:
Uhhhuhhhh
Uhuh

Ijoba orun
Ere Onigbagbo o
Ijoba orun
Ere Onigbagbo o

Ma je n kuna
Baba
Mu mi dele o
Ma je n kuna
Baba se
Mu mi dele o

Owo ti mo ni
ko le mu mi dele o
Moto ti mo ri ra
ko le wa mi dele o
Ore ti mo ni
ko le sinmi dele o
Gbogbo iwe ti mo ri ka
won o le gbe mi dele o

Ma je n kuna
Baba
Mu mi dele o
ki n ma ku sajo bi efin
Mu mi dele o
Aye loja, oorun ni ile
Mu mi dele o
Aye loja yi, oorun nile se
Mu mi dele o

Mu mi dele o (x8)
Ma ma je n kuna
Baba ooo
Baba ooo
Mu mi dele o (x5)

Ile ogo
Ile ayo, Ile ayo
Ile alafia
Ile ogo
Ile ayo, Ile ayo
Ile alafia

Ijoba orun
Ere onigbagbo o
Ijoba oorun
Ere onigbagbo o
Ma je n kuna
Posted by: Emmanuel
Did you notice any error in our lyrics or on our pages. Pls report such errors so as to help us serve you better.

TOP 5 POSTERS

  • Poker - 15
  • Biyi Babalola - 11
  • Miss Tee - 11
  • Mycks - 4
  • Deji - 4

Copyright 2006 - 2012 ennovateNIGERIA. All rights reserved.   Terms and Conditions  |  About Us